109.The Disbelievers

  1. Sọ pé: "Ẹ̀yin aláìgbàgbọ́
  2. Èmi kò níí jọ́sìn fún ohun tí ẹ̀ ń jọ́sìn fún
  3. Ẹ̀yin náà kò jọ́sìn fún Ẹni tí mò ń jọ́sìn fún
  4. Èmi kò níí jọ́sìn fún ohun tí ẹ jọ́sìn fún sẹ́
  5. Ẹ̀yin náà kò kú jọ́sìn fún Ẹni tí mò ń jọ́sìn fún
  6. Tiyín ni ẹ̀sìn yín, tèmi sì ni ẹ̀sìn mi