108.Abundance

  1. Dájúdájú Àwa fún ọ ní ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ oore
  2. Nítorí náà, kírun fún Olúwa rẹ, kí o sì gúnran (fún Un)
  3. Dájúdájú, ẹni t’ó ń bínú rẹ, òun ni kò níí lẹ́yìn